Lati Inu Dáyárì Ọmọ Kilásì Àárin Kan [electronic resource] : Iriri Ọmọde
Kumawat, Ashok2021
eBook
Àpèjúwe KúkúrúNinu ìwé yii Mo ti ṣàpèjúwe awọn akitiyan igbé ayé mi ni kọlẹji. Mo pinnu lati kọ ìwé yi nigbati ó jẹ wipe n kò ni awọn ọrẹ, n kò mọ bi awọn ìdánwò ipari simẹsità ti yunifásítì se ri, ti mo si pàdánù awọn ìdánwò mi. Lẹhin ọpọlọpọ akitiyan, mo se awọn ìdánwò ipari simẹsità, mo si kọ awọn iriri mi ni kọlẹji sinu ìwé yi.Àpèjúwe Ní KíkúnNinu ìwé yii Mo ti ṣàpèjúwe awọn akitiyan igbé ayé mi ni kọlẹji. Mo pinnu lati kọ ìwé yi nigbati ó jẹ wipe n kò ni awọn ọrẹ, n kò mọ bi awọn ìdánwò ipari simẹsità ti yunifásítì se ri, ti mo si pàdánù awọn ìdánwò mi. Lẹhin ọpọlọpọ akitiyan, mo se awọn ìdánwò ipari simẹsità, mo si kọ awọn iriri mi ni kọlẹji sinu ìwé yi.
Author:
Imprint:
[Place of publication not identified] : Tektime, 2021
Collation:
1 online resource (1 text file)
ISBN:
9788835427162
Language:
Yoruba
BRN:
4274082